Oba Mimo
Oba mi olola
Oba mi ologun
Oba imole
Kabiyesiii Olodumare
Eni to da aye ati orun
To da mi laworan re
Abiyamo ode orun
Adabatubu Olodumare
Oba Mimo
Oba to mo mi
Oba to mo mi
O mean eh si mi
Shebi iwo loni kin maa min
Lo ni kin maa yo
Lo ni kin maa yan fanda oo
Ninu ogo gan gan lo tin bo
Ninu ola nla nla lotin shishey
Ah un o yin o logo
Un o shey o loba
Un o shey afe ri re
Oba mi olola
Oba mi olola
Ti baba lase ooo
Ti baba loye
Ti baba lase ooo
Ti baba loye
Ni gbogbo Oro re
Emi mimo baa le mi
Ara mi ti ya dada
Ti baba Alase
I lean on
Oro ti gbenu omo eda sise
On your word
Eyi ti n gbenu Omo eda di ogo
Ayo ayo ahh
Olodumare
Oba akoda
Oba aseda
Ayo ayo waa
Oba ti n sorooo be naa ni o
Hmm...
Ti baba lase (I lean on)
oh oh oh
Ti baba loye
Ti baba araye (on your word)
oh oh oh
Ti baba loye
Nigba wan gbogun wa wa ah(Ayo ayo ahh)
Emi mimo baa le mi
Ara mi to ya dada(Ayo ayo waa)
Ti baba Alase
Oro mi atata
Baba alayi lenikan
Eni to fe mi o
Ki aye to mo mi
Social Plugin